ẸNI ỌKAN MI (MY DEAREST) – Yoruba Poem

By |2020-07-23T17:17:31-04:00March 6th, 2017|Categories: Culture and Race|Tags: |

Ó yá, ẹni ọkan mi, tẹ́'wọ àdúra: Mo gba àdúrà yi fún o ati fun gbogbo idile re ni odun 2017 yi wípé l'ónìí àti l'ójó gbogbo... Ojú kò  ní tì e. Ayé kò ní yò e. Olórun kò ní gba ògo re fún elòmíràn láéláé. Igbá ilé re kò ní fó. Aso ìbora re kò ní [...]